#Ooduarere
Explore tagged Tumblr posts
newsnigeria · 1 year ago
Text
Reno Omokri shakes the table and bursts a bubble again as he schools an Obidient on Nigerian history
Tumblr media
Earlier today, a post was shared on Ooduarere where Reno Omkori replied to an Obedient on twitter/X. He has done it again. This time around he schooled an obedient that was trying to play the victim on Aburi Accord. The Twitter user by the ID @Benjami03827700 shared the screenshot below. See what he wrote below.
Tumblr media
@renoomokri: Dear Obi, Thank you for your feedback. On Aburi, you may want to consider the following facts. When Major General Aguiyi-Ironsi abrogated regionalism and promulgated Decree Number 34 on May 24, 1966, which effectively ended regionalism, took control of all resources, including oil (all resources, including oil used to belong to the regions before Ironsi's decree), which had hitherto belonged to the regions, and domiciled them in his military government.  Other members of the Supreme Military Council alleged that Ironsi did not consult them before promulgating the decree. It is not known if their allegation is true. However, Ironsi's Attorney General, Chief Gabriel Chike Michael Onyiuke, later said Ironsi did not need to consult them. Also, perhaps naively, ALL of Ironsi's advisers were Igbo, like him.  They included Chief Francis Nwokedi, Dr. Pius Okigbo, and Colonel Patrick Anwunah. Calls for him to appoint at least one token non-Igbo fell on deaf ears. That decree ignited the counter-coup of July 29, 1966, in which Ironsi was killed and replaced with Lt. Colonel Yakubu Gowon, who did not participate in the coup but was a compromise candidate since he was a Northerner, to appease the North and a Christian, to placate the South. All Military Governors accepted him except Ojukwu.  Eventually, the then Ghanaian military leader, General Ankrah, invited Gowon and Ojukwu for a peace meeting in Aburi, Ghana, between January 4-5, 1967. Agreements were reached, including that Gowon would broadcast first, AFTER CONSULTATIONS, followed by Ojukwu. However, upon return, Ojukwu made his broadcast first, which shocked other regions and jeopardised Gowon, who was almost removed by those who made him Head of State.  Please note that Gowon had no control of the troops. He was, at that time, just a titular Head of State. The real power was domiciled with Colonel Murtala Muhammed until Murtala was militarily humiliated by the Biafrans at Abagana on March 31, 1968, after which Gowon relieved him of his command, and Colonel Obasanjo later became the darling of Gowon due to his military effectiveness against Biafra.  You must understand that at that time, Ojukwu had full dictatorial powers in Biafra, but Gowon was hanging on a rope in Lagos. As a result of Ojukwu's broadcast, Gowon issued Decree Number 8, and later, on May 27, 1967, broke Nigeria into 12 states. That decree would NEVER have been passed were it not for Ojukwu's broadcast. Ojukwu rejected both actions and declared the Republic of Biafra on May 30, 1967, which ignited a police action by Gowon's government on July 6, 1967.  Things degenerated into war, which did not end until Biafra's defeat on January 15, 1970, after Ojukwu fled on January 11, 1970. The war may have been prevented if Ojukwu broke away with only the East Central state, which was homogeneously Igbo. However, he insisted on the whole of Eastern Nigeria, which included non-Igbos in Calabar and Rivers, whose leaders, like Isaac Boro and Ken Asari-Wiwa, rejected Biafra. Even within Biafra, prominent Igbos, like Dr. Nnamdi Azikiwe, did not support Ojukwu's actions.  They felt that a diplomatic solution could be reached. But after Colonel Ojukwu began executing his friends, like Major Emmanuel Ifeajuna, Colonel Victor Banjo, Philip Alale, and Sam Agbam, amongst others, for treason, they all kept quiet and began plotting to escape Biafra.  This is why Nnamdi Azikiwe escaped from Biafra and turned up in Lagos in 1969, sitting beside General Gowon, declaring support for the Federal Military Government and condemning Colonel Ojukwu, whom he blamed for the deaths of millions of Biafrans. If Colonel Ojukwu had only waited for Gowon to broadcast after Aburi, there would likely have been no war. Thanks again, and may God bless you.  #TableShaker
Tumblr media
Read the full article
0 notes
newsnigeria · 4 years ago
Text
Oodua words for today
Tumblr media
Today's Oodua words Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC
Tumblr media
Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke sí i báyìí,lẹ́yìn tí àjọ NCDC tún kéde okòólélọ́ọ̀dúnrún dín méje èèyàn tí èsì àyẹ̀wò wọn sẹ̀sẹ̀ jáde. Ní báyìí, èèyàn ẹgbẹ̀rún méje, àti . òjìlélẹ́gbẹ̀rin dínkan (7839) ni àkọsílẹ̀ wà pé ó ti ní àrùn náà ní Nàìjíríà. Àkójọpọ̀ àwọn ìpínlẹ̀ tí èsì tuntun náà ti wá nìyí. Àjọ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ arun l’órílẹ̀èdè Nàìjíríà, NCDC, kéde pé ènìyàn igba àti márùndínláádọ́rin ni àyẹ̀wò fihàn pé ó tún ní àrùn ni apinni léèmí Kòrónáfairọ̀ọ̀sì Naijiria. Nínú èsì àyẹ̀wò náà, ìpínlẹ̀ Èkó ní èèyàn mẹ́taleláàdóje, Ọ̀yọ́ ní mẹtàlélọ́gbọ̀n, Edo sì ní méjìdínlọ́gọbn. àwọn tó ti ní l’órílẹ̀èdè Nàìjíríà jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje, àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta lé mẹ́rìndinlọ́ggbọ̀n (7526). Ẹgbẹ̀rún méjì àti mẹ́rìnléláàdọ́sàn (2174), ti rí ìwòsàn, okòólérúgba lé kan (221) sì ti kú. Fẹ́mi Akínṣọlá Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Oodua Fantasy: Creatures from The Forest of No Return:
Tumblr media
Kurekure (Ghomid) observing a (Yinmiyinmi) Dung Beetle Adeboye Adegbenro Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Tumblr media
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn àti Ìlàkàkà wọn fún àṣeyọrí gbogbo Ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin pẹ̀lú ìdọ́gba pẹ̀láwọn ọkùnrin ló gbòde gẹ́gẹ́ bíi ohun òjútáyé lásìkò àjọyọ̀ àyájọ́ obìnrin lágbàáyé ti ọdún yìí. Àkọmọ̀nà àyájọ́ náà fún ọdún yìí ni “ajàfẹ́tọ̀ ìbáradọ́gba ni mí: mímú ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ṣẹ.” Nínú ọ̀rọ̀ tiwọn, àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé rọ àwọn èèyàn gbogbo láti jí gìrì gbógun ti àwọn ìpèníjà sísọ àìdọ́gba láàrin ẹ̀yà ẹ̀dá gbogbo. Nínú ọkàn ò jọ̀kan ọ̀rọ̀ tí wọ́n ṣọ ní ìrántí àyájọ́ yìí, àwọn obìnrin ní oríṣìríìṣí Ìlànà iṣẹ́ ajé gbogbo sọ̀rọ̀ lórí ìpèníjà tí wọ́n ń dojúkọ; paàpá jùlọ láàrin àwọn ọkùnrin lẹ́nu iṣẹ́ ajé gbogbo léyìí tí ò jẹ́ adínàgboòkú. Fẹ́mi Akínṣọlá Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Ilé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létí
Tumblr media
Ilé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létí Ejo ti ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja da ni ojo ketala, osu yii ni egbe oselu APC ni awon ko fara mo. Eyi ko tii saba waye ri ni orileede yii, ki ile-ejo giga da ejo ki awon kan wa ni won ni lati tun se ayewo re. Ejo naa lo fagi le ibo to gbe David Lyon wole gege bi gomina ipinle Bayelsa labe egbe oselu APC. Awon egbe PDP ni won pejo pe iwe eri igbakeji gomina naa ko moyan lori rara. Won ni orisiirisii oruko lo wa lori iwe eri igbakeji gomina naa, iyen Seneto Biobarakuma Degi-Eremienyo. Ile ejo ni ki awon to ni ejo ko te awon lorun fa asise awon jade sugbon ko si agbejoro to le fa asise Kankan jade ninu ejo naa. Eyi mu ki ile-ejo giga naa fi milionu mewaa naira fa egbe APC leti. Ile-ejo ni ki won ma se je ki iru re waye mo. Láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Akiyesi Pataki
Tumblr media
Arákùnrin oníṣègùn oyinbo tó jẹ́ ọmọ bíbí Nigeria to wá n'ilu USA, fi ọrọ ìyànjú yí ranṣẹ fún anfaani ara wa. Jọ̀wọ́ ká, kí ó sì mú lo fún ìtọ́jú ara rẹ. Dr. A. Malgwi Ọna ti àwọn ọdọ wá lóde òní, ngba ni àìsàn kidirin jẹ ohun tó ndẹru báni. Mo nfi itẹjade yí ranṣẹ torí kò le ràn wá lọ́wọ́ nínú ewu àìsàn kidirin. Jọ̀wọ́ fara balẹ láti ka ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ yí: AKIYESI PATAKI KIDIRIN WA GBA ÀMÓJÚTÓ TÓ PÉYE Bí ọjọ́ méjì sí ìgbà tá wá yí, ní a gbọ ìròhìn ikú ọkàn ni àwọn òṣeré ori itage ọmọ ilẹ̀ wá ti àìsàn kidirin ṣekú pá. Bakanna, Minister alabojuto Iṣẹ́, Honourable Teko Lake wá nílé ìwòsàn ni ẹsẹ kan ayé, ẹsẹ kan ọrùn, nítorí àìsàn kidirin yí na ni. Idanilẹkọ yi dá lórí bí a ṣe lè toju ara wa ti ao ni bá wọn nipin ninu àìsàn kidirin yí. EYI NI ONA MẸ́FÀ PATAKI TI ÀÌSÀN KIDIRIN FI ŃṢE ENIYAN Dídá itọ mọ àpò itọ fún ìgbà pipẹ lai tọ, jẹ́ ọ̀nà àkọ́kọ́ tí ó má ń fà àìsàn kidirin. Tí ile itọ wá bá ń kùn ju bó ṣe yẹ lọ, o má nba ilé itọ wá jẹ́. Itọ yí tí ao tọ jáde nílé itọ wá, kún fún ọpọlọpọ kòkòrò aifoju ri ti a n pe ni bacteria, ti wọn ba npẹ ju nílé itọ wá, wọ́n má npọ sì ni kíákíá. Èyí má fún àwọn kokoro yí lanfani láti máa padà sínu kidirin wá àti àwọn ọ̀nà miran ti wọn lé gba jáde, eyi má ńṣe jamba fún kidirin wá púpò. Nígbà miran, àwọn kòkòrò yí ni ó má nfa aisan atọsi ọlọyun àti orisirisi àwọn aisan bí nephritis àti uremia. Tí itọ bá gbọn wá, kí a tọ itọ yí lásìkò tó yẹ.Jíjẹ iyọ pupọ ju, tún jẹ́ ọna miran ti àìsàn kidirin fi ń mú wá. Ao gbudọ jẹ́ iyọ ju ìwọ̀n 5.8 grams lọ ní ijoko ẹkan ṣoṣo.Jijẹ ẹran pupọ ju. Èròjà protein to wá nínú ẹran, to ba pọ ju má npa kidirin wá lára. Kí èròjà protein ṣe ń kuro lára ẹran tí a ń jẹ, bẹ ní kemika ammonia na ma ń jáde pẹlu rẹ. Kemika ammonia yí ko ni ìwúlò kankan lára. Tí ammonia yí bá ti ń poju bó ṣe yẹ lọ, ó má ńṣe àkóbá fún kidirin wá. Jíjẹ ẹran pupọ ju má njẹ ki ammonia yí po jù nínú kidirin wá ti yio ba kidirin wá jẹ́.Mímú kafini pupọ ju. Kafini jẹ́ lára àwọn èròjà tí ó má nwa nínú àwọn minira bí Coca-Cola, nescafe tea àti òbí tí a njẹ. Kafini má njẹ ki ifunpa wá (blood pressure) ga ju bó ṣe yẹ lọ. Tí ifunpa wá bá nga ju, ó má ń ṣàkóbá fún kidirin wá. Torinaa, ẹ jẹ ki a sá fún mímú minira bí coke ati mimu nescafe pupọ ju àti jíjẹ òbí pupọ ju.Áìmu omi dada. Kidirin wá nílò omi láti ṣíṣe daradara, tí a kò bá mú omi daradara kidirin wá má ń ṣíṣe afipa ṣe àti wipe àwọn ìdọ̀tí (Toxins) tí kidirin wá yẹ kó sẹ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ wá, yio tun padà sára wá. Nítorí náà, ẹ jẹ ki a ma mu omi daradara, o kere ju kí a má mu omi pure water mefa lojumo. Ọ̀nà tó rọrùn láti mọ bóyá a ń mú omi to boti yẹ. Wò awọ itọ tó ń tọ bóyá ó pọn tàbí ó mọ bí omi. Tí ó bá pọn, ó kí mu omi tó. To ba mọ, ó nmu omi tó.Áìbìkítà láti ṣe ìtọ́jú aisan tó bá ńṣe wá lásìkò àti botiyẹ. Ẹ jẹ ki a ma tètè bójú tó àìsàn tó bá ńṣe wá lásìkò àti botiyẹ. Ẹ má ṣe ayẹwo ara wa nípa lílo àwọn ẸRỌ IFUNPA, ẸRỌ ITỌ SUGAR, ki a ma lọ rí dókítà wá lore kórè. Kí a má lo àwọn ogún wá nígbà tó yẹ. Ẹ jeki a rán ara wa lọ́wọ́. Ọlọ́run a ra wá lọ́wọ́ àti àwọn ẹbí wá lọwọ orisirisi àìsàn. Ẹ̀JẸ̀ KÍ A SA FUN ÀWỌN OGUN WỌNYI WỌ́N ŃṢE ÌPALÁRA FUN ARA WA, WON JE OGUN TÓ LEWU GIDI GAN-AN. *D-cold *Vicks Action-500 *Actified *Coldarin *Cosome *Nice *Nimulid *Cetrizet-D Àwọn ogún yí ni èròjà Phenyle Propanol-Amide PPA. Èyí má nfa àìsàn rọparọsẹ(STROKE). Àwọn ogún yí ni ìjọba USA kò gbà láyé nilẹ wọn. Jọ̀wọ́, kí ó tó pá ìtẹ́ jáde yí rẹ, rán ọrẹ rẹ lọwọ nípa fífi ìtẹ́ jáde yí ranṣẹ si. Nípa ṣíṣe bayi, ó lè ràn ẹnikan lọwọ. Fi ranṣẹ sì ọpọlọpọ ènìyàn.. Àwọn dókítà ni ilu United States tí ṣe àwárí àìsàn jẹjẹrẹ kan tó ndamu ọmọ ènìyàn lamu, ohun tó ń ṣokùnfà àìsàn yì ni èròjà kan tí a npe ni Silver Nitro Oxide. Silver Nitro Oxide ni kemika tí wọ́n fi bo nọmba tó wà lára Recharge card, tí a bá ra recharge card, e ma fi ekana ha kemika yí tí ó lè fà àrùn jẹjẹrẹ yí. Ṣé alábàápín atẹjade yí pẹlu awọn olólùfẹ́ rẹ. ÌRÒHÌN ÌLERA TÓ ṢE PÀTÀKÌ Gba ìpè lórí fóònù rẹ sì etí osi.Má ma lo ogún òní horo pẹlu omi tutu.Má ma jẹ onjẹ to wúwo lẹhin ago marun irọlẹ.Mú omi daradara lowurọ, mú omi niwonba lalẹ.Àkókò to dára jù fún orun sísun ju ni àgó mẹwa alẹ sì àgó mẹrin arọ.Ó kò gbọ́dọ̀ sún ni kété tí ó bá lo ogún tàbí jẹun tán.Tí agbára batiri fóònù rẹ bá ti kú ìlà kan, ó kó gbọ́dọ̀ gba ìpè, torí wipe, àwọn agbára aifoju tí fóònù rẹ má nto ìlọ́po 1000 tí ole ṣe àkóbá fún ìlera rẹ. Ǹjẹ́ ole fi ite jáde yí ranṣẹ sì àwọn ènìyàn tí ó bìkítà fún? Èmi ti ṣe bẹ. Anu ṣíṣe ó nan wa lowo ṣùgbọ́n imọ jẹ agbára. Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Ìjọba Àpapọ̀ Kò Gbẹ́sẹ̀lẹ̀ Lé Owó Tó Tọ́ Sáwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ L‘ọyọ
Tumblr media
Ìjọba àpapọ̀ kò gbẹ́sẹ̀lẹ̀ lé owó tó tọ́ sáwọn ìjọba ìbílẹ̀ l‘Ọyọ Fẹ́mi Akínṣọlá Lórí ọ̀rọ̀ kan tó gbà gboro kan pé àgbẹjọrò àgbà orilẹ̀-èdè Naijiria, Abubakar Malami ti pàṣẹ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo láti gba àwọn alága káńṣù ti wọ́n yọ nípò pada, Ìjọba Ọyọ ti fèsì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà. Nígbà tó ń sẹ̀rí ọ̀rọ̀ náà, Akọ̀wé ìkéde ìjọba ìpińlẹ̀ Oyo, Ọgbẹ́ni Taiwo Adisa ní, ìrọ tó jìnà sí òtítọ ni nítori pé òun kò tí ì rí lẹ́ta kankan tó jọ bẹ́ẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Malami. Ó fí kún un pé kò sí ìgbà kankan tí Malami jáde láti sọ pé òun kọ lẹ́tà ránṣẹ́ si ìpínlẹ̀ Oyo, pẹ̀lú àfikún pé, ó se pàtàki ki àwọn akọ̀ròyìn máa ṣe ìwádìí wọ́n dáradára, ki wọ́n tó máa tan ìròyìn tí kò fi ìdí múlẹ̀ káàkiri. Lórí àhesọ ọ̀rọ̀ kan tó sọ pé, ìjọba ìpinlẹ̀ Oyo kò rí owó gbà láti ọ̀dọ̀ ìjọba àpapọ̀ fún àwọn ìjọba ìbilẹ̀, nítori pé àwọn Alága fìdíẹ ni wọ́n fi sí ìjọba Káńsù Adisa ní òfo ọjọ́ kejì ọjà ni ọ̀rọ̀ ọ̀hún. ” Ẹni tí wọ́n bá nà ló yẹ kí ara máa ta, tí ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ kò bá rí owó gbà, ẹnu ìjọba ìpínlẹ̀ ni ẹ ó ti gbọ́ kìí ṣe ẹnu àwọn ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀. Nítorí náà, òfúùtù fẹ́ẹ̀tẹ̀ ni Ìròyìn tó ní àwọn ��jọba ìbílẹ̀ ní Ọyọ kò rí owó tó tọ́ sí wọn gbà láti ọ̀dọ̀ Ìjọba àpapọ̀.” Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩
Tumblr media
Pásít��̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩ Gbaju-gbaja Pastor ti gbogbo eniyan mo si Pasito Chriacus to je omo bibi ipinle Anambra amo ti o fi agbegbe Ikotun ni ilu Eko se ibujokoo ni eru Olorun tun ba pelu ohun toju re ri. Okoowo karakata ni Pasito Chriacus n se tele ni ilu Ikotun ki o to di pe o ni Olorun pe oun lati sise fun Un. O ni lati igba ti oun ti bere ise ojise yii ni iyawo oun ti bere ogun pe oun ko gbele mo, oun ko foju to omo ati bee bee lo. Eyi ni iyawo naa si gun le pe ooto ni oko oun n so, ko ri aaye fun oun ati awon omo marun-un ti oun bi fun un mo lati igba to ti bere ise iranse naa. Chinyere to je iyawo re ni eyi lo faa ti oun fi wa eni to maa mu ki inu oun dun ti awon si jo n sere. Pasito ni awon ara adugbo ti n so oro yii ti pe pe iyawo oun n yan ale ti oun ni ko le sele si iyawo ojise Olorun. Afi bi emi Olorun se ni ki oun wale ni ojo kan ti iyawo oun ko lero, bi oun se ba okunrin miiran lori iyawo oun niyi ni ori beedi awon. Pasito ni Satani to n gbe inu iru obinrin yii ni o mu ki oun lee danu lasiko naa ki o maa ba ba ise Olorun je lara oun. Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan
Tumblr media
Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú abínibí rẹ̀ nípìńlẹ̀ Bayelsa. Nínú ọ̀rọ̀ orí fóònù náà, Ààrẹ Buhari kò fi bí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe ba òun nínú jẹ́ pamọ́. Ó ṣàkàwé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìṣẹ̀lẹ̀ ìbànújẹ́ ńlá tí ó sì kù díẹ̀ káátò. Ààrẹ tún kan sárá sáwọn ṣọ́jà tó ń ṣọ́ Ilé Ààrẹ Jonathan fún bí wọ́n ṣe kojú ìjà náà gẹ́gẹ́ bí akin. Ó wá bá àwọn ẹbí ọmọ ogun tó ṣubú lójú ìjà náà dárò. Ààrẹ Buhari wá fi dá àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà lójú pé àbò tó yẹ ń bẹ fún ẹ̀mí Ààrẹ àná náà àti gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà láì yọ ẹni kan sílẹ̀ àti pé ààbò ni yóó túbọ̀ máa jẹ ìṣèjọba òun lógún. Ni Ọjọ́ Ìṣẹ́gun ni ìròyìn jáde síta pé àwọn agbébọn kan kọlu ilu Otuoke tó jẹ́ ìlú Ààrẹ àná, Ọ Omọ̀wé Goodluck Jonathan tí wọ́n sì pa ṣọ́jà kan níbẹ̀. Fẹ́mi Akínṣọlá #iroyinowuro Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Òòlù ìdájọ́ ré bá Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn, owó ìtánràn, ìgbélé tipátipá, iṣẹ́ ìsìnlú bíi bọ̀kílẹ̀ àfojúdi .
Kò sí n tó burú kí abẹ òfin ba Ògbó Awo tó bá ń se bí ọ̀gbẹ̀rì . Ilé ẹjọ́ ti dá gbajúgbajà òṣèré sinimá, Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ Abdulrasheed Bello lẹ́jọ́ pé ó jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án pé ó lòdì sí òfin kónílégbélé tí ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó gbé kalẹ̀ lórí dídẹ́kun àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus nípìńlẹ̀ Èkó àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé ẹjọ́ rán àwọn méjéèjì lọ sí iṣẹ́ ìsìnlú fún wákàtí mẹ́ta lóòjọ́ fún ọjọ́ mẹ́rìnlà, yàtọ sí ọjọ́ Sátidé àti Àìkú. Bákan náà ni iléẹjọ́ ní kí wọ́n san owó ìtanràn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn náírà. Bákan náà ni ìdájọ́ ọ̀hún tún ní kí ọ̀kọ̀ọ̀kan lọ́kọláyà náà yóó lọ sí ibùdó pàtàkì mẹ́wàá ní ìpínlẹ̀ Èkó láti ṣe ìdánilẹ́kọ́ọ̀ àti ìlanilọ́yẹ lórí ìjìyà tó wà fún ẹni tó bá ṣoríkunkun sí òfin kónílé ó gbélé. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbọdọ̀ fi orúkọ àti nọńbà ìbánisọ̀rọ̀ gbogbo àwọn tó kópa níbi àjọyọ̀ náà. Bákan náà nìròyìn míì ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, Azeez Fashola tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí Naira Marley tí àwọn agbófinró tí kọ́kọ́ kéde ṣaájú pé àwọn ń wá ló tí fúnra rẹ farahàn báyìí ní àgọ́ Ọlọ́pàá. Ìròyìn ń bọ lórí rẹ̀ láìpẹ́ ẹ fojú sọ́nà Òòlù ìdájọ́ ré bá Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn, owó ìtánràn, ìgbélé tipátipá, iṣẹ́ ìsìnlú bíi bọ̀kílẹ̀ àfojúdi . Fẹ́mi Akínṣọlá Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Omijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́
Omijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́ Bá a pẹ́ tí tí, bí ẹni rebi,bi èmi sì gùn gùn gùn bí okùn tó gùn,ikú lòpin èèyàn. Ìjọ aláyé ti dáyé, lakásọlérí ti í ṣunkún ara a wọn, kò ṣẹ́ni tí ò níí kú, kò ṣẹ́ni tí oko baba rẹ̀ kò ní dìgbòrò. Ìlúmọ̀ọ́ká àgbà ọ̀jẹ̀ nídìí iṣẹ́ tíátà, Lere Paimọ ti sàlàyé pé lọ́pọ̀ ìgbà, àìrìríjẹ́, àìrímú tàbí ìrònú má a ń jẹ́ kí ọjọ́ ogbó dagun. Lásìkò tó ń bá akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ lórí ikú tó pa àgbà ọ̀jẹ̀ nínú tíátà míràn, Pa Kasumu, Paimọ ní ó yẹ kí àgbàlagbà máa rí àánú gbà, láti ọ̀dọ̀ àwọn èèyàn àwùjọ, kìí ṣepé èèyàn ń tọrọ. Àgbà ọ̀jẹ̀ nínú isẹ tíátà náà ní omijé bọ́ lójú òun nígbà t’óun rí olóògbé náà gbẹ̀yìn, nitori ipo to wa. Ó wá se àdúrà pé kí Aláwùràbí dí ẹbí tí olóògbé náà fi sílẹ̀ mú, kí Ọlọ́run forí jin òkú. Nínú ọ̀rọ̀ tí ẹ̀, Salami sàlàyé pé ènìyàn tó ṣe é mú yangàn ni Pa Kasumu nígbà ayé rẹ̀, o si tún jẹ́ ẹni tí ó máa ń tèlé òfin àti ìlànà iṣẹ́ rẹ. Ọga Bello tẹ̀síwájú pé “Ó bani níńú jẹ́ sùgbọ́n kò sí nǹkan tí a le ṣe sí àṣẹ Ọlọ́run. Saájú àsìkò yìí ni a ti ń sàfẹ́rí Pa Kasumu nítorí ó ti tó ọdún díẹ̀ sẹ́yìn tí kò ti lè darapọ̀ mọ́ wa mọ́ láti ìgbà tí ó ti ṣe àìsàn” “Àdúrà mi ni pé kí Ọlọ́run tẹ́ ẹ sí afẹ́fẹ́ rere, kí ó sì tu àwọn ẹbí olóògbé nínú” Toyin Adewale, Jaiye Kuti, Toyin Adegbola àti Yomi Fabiyi naa wà lára àwọn òṣère tí o ti ń ṣe elédè lẹ́yìn rẹ Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, Fabiyi ní “Ẹni iyì àti ẹ̀yẹ ni Pa Kasumu tí mo sì ní ìfẹ́ rẹ̀ gídí, mò ń ṣelédè lẹ́yìn rẹ̀ fún iṣẹ́ ribiribi tó ṣe nínú iṣẹ́ tíátà.” Ní ti Toyin Adegbola, Ó ní “O dárọ Kayode Odumosu, kí Ọlọ́run dẹlẹ̀ fún, kí ó sì tẹ sí afẹ́fẹ́ rere. Foluke Daramola- Salako ló kéde ikú Pa Kasumu lórí àtẹjiṣẹ́ instagram rẹ, gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, Kayode Odumosu kú ní ilé ìwòsàn kan ní Abeokuta lásìkò àisan ranpẹ. Fẹ́mi Akínṣọlá Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì
Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é.. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì Fẹ́mi Akínṣọlá Àṣà àti ìṣe wà nínú n tíí ṣàfíhàn èèyàn bí ọmọ ọkọ tàbí ọmọ ìdàkejì n ló díá fún bí onírúurú ohun tẹ́ ẹ̀ tilẹ̀ mọ pé ó wà láyé yìí se dohun àfojúrí níbi ayẹyẹ àjọ̀dún àṣà ọdún yìí ní ipinlẹ Èkìtì, . Adarí iléeṣẹ́ Àṣà ni ìpínlẹ̀ Èkìtì, Wale Ojo sọ fún akọ̀ròyìn pé àwọn ń kó àwọn àṣà àwọn jáde láti ṣe àfihàn rẹ̀ fáráyè ni. “A sọ ijó di owó, ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Èkìtì, obìnrin lè ṣe é”. Ọ̀gbẹ́ni Wale sọ pé Èkìtì Festival ti mú ọlá àti oríire wọ ìlú Èkìtì, “ó ń gbe ọgbọ́n inú àti ìmọ̀ àwọn ọ̀dọ́ jáde síta”. Ó tẹ̀síwájú pé gbogbo ìlú tó wà ní Africa ló kù tí Èkìtì máa fìwé pè lọ́dún 2020 láti wá wo ọgbọ́n, ìmọ̀ àti òye ti Ọlọ́run fi sọlọ̀ sí ìlú Èkìtì. Lóòtọ́ lóòtọ́, kò sí àṣàdànù nínú àwọ́n afihan ohun agbaṣa ga to waye nibi EKiti Festival 2019. Ṣé ẹ mọ̀ pé Ekiti ni ìlú tí Ògún Lákááyé wọlẹ̀ sí? Ìlú Ọrúnmìlà náà, Èkìtì ni. Èṣù tó má a ń dá àbò bo àwọn èèyàn tirẹ̀, Èṣù Ẹlẹ́gbára tó máa ń gba àwọn eeyan lọ́jọ́ ibi bá dé, ìlú Ekiti ni gbogbo wọn ti wá gẹ́gẹ́ bí adarí àṣà ìpínlẹ̀ náà ṣe sọ ọ́. Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti, Erelú Bísí Fáyemí kádíì ètò àjọ̀dún náà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ìwúrí nípa Ekiti pé “Orin Ekiti dá yàtọ̀, ijó wọn, òkè ńlá ńlá àtàwọn nǹkan tó jẹ́ pé owó làwọn èèyàn fi lọ ń wò wọ́n níbòmíràn”. Iroyinowuro Read the full article
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Check out New Post published on Ọmọ Oòduà
New Post has been published on http://ooduarere.com/news-from-nigeria/breaking-news/i-love-oodua-wins/
I love Oodua wins
A poll between I love Yoruba or I love Oodua took place and latter won by a large margin. Ooduarere.com favourite cap on Twitter profile pic and facebook will be replaced with I love Oodua. Other social media profile picture will be replaced later and this page will be updated each time.
Ooduarere.com
Before and after profile picture of Ooduarere.com Twitter page.
Before and after profile picture of Ooduarere.com Facebook page.
Before and after profile picture of Ooduarere.com Instagram page.
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Check out New Post published on Ọmọ Oòduà
New Post has been published on http://ooduarere.com/news-from-nigeria/breaking-news/oodua-wins/
Oodua wins
0 notes
newsnigeria · 5 years ago
Text
Check out New Post published on Ọmọ Oòduà
New Post has been published on http://ooduarere.com/art/a%e1%b9%a3a-yoruba/a%e1%b9%a3iri-pasito-to-n-fi-soosi-%e1%b9%a3e-ogba-were-tu/
Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú
Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú
Fẹ́mi Akínṣọlá
Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn rẹ̀ tí ó wà ní àgbègbè Ijegun ìpínlẹ Eko gẹ́gẹ́ bi ẹ̀wọ̀n fún àwọn alárùn ọpọlọ àti àwọn tí wọ́n ní àrùn kan tàbi òmíràn.
Ìròyin sọ pé ọlọpàá mú Ojo lẹ́yìn ti ẹ̀ka ọlọpàá Isheri-Osun tú àwọn ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún sílẹ̀ nínú ilé ìjọsìn rẹ̀ ní ọjọ́rú lẹ́yìn tí àwọn àjọ kan ti kìí ṣe ti ìjọba ta ilé iṣẹ́ ọlọpàá lólobó.
Àbẹ̀wò sí àwọn ọlọ́pàá sílé ìjọ náà ní ọjọ́bọ sàfihàn pé àwọn ènìyàn kan wà lóríso bí ẹran àmúso tí àwọn míràn sì ń sọ̀rọ̀ tí kò jọrawọn.
Ojo sàlàyé fún àwọn akọròyìn pé òun so àwọn ènìyàn náà mọ́lẹ nitórí ipò ti wọn wà, àti pé ọ̀pọ̀ wọ́n ni òbí wọ́n mú wá fún ìtúsílẹ̀ àti ìwòsàn.
O ní ” a so àwọn ènìyàn yìí mọlẹ̀ nítori ipò ti wọ́n wà, tí a ò bá so wọ́n mọ́lẹ̀ wọ́n á sálọ, wọ́n ti ko mi sí wàhálà sẹ́yìn, nítori náà ni mo ṣe so wọ́n tí ara wọ́n bá ti yá ni a máa ń tú wọ́n sílẹ̀.” Pásítọ̀ Ojo ní, “Ibí kìí ṣe ilé ìwòsàn ti wọ́n ti ń wo àrùn ọpọlọ sùgbọ́n ọ̀pọ̀ wọ́n ni wọ́n ti kọ́kọ́ gbé lọ sí ilé ìwòsàn tí wọ́n ti ń wo wèrè kí wọ́n tó gbé wọ́n wá síbi.”
“Bí osù mẹ́ta sí mẹ́rin ni a fi máa ń so wọ́n mọ́lẹ̀, àwọn ẹbí wọ́n sì ní yóó máa fún wọn lóunjẹ, àwọn ẹbí àwọn míràn máa ń wá lójoojúm, àwọn míràn ọsẹ̀-ọ̀sẹ̀, nígbà ti àwọn míràn ń gbé pẹ̀lú ẹbí wọ́n nínú ìjọ” Ọ̀kan nínú àwọn tí wọ́n ti so mọ́lẹ̀ fún oṣù mẹ́jọ níbẹ̀, Adewale Adetona sàlàyé pé wọ́n jí òun gbé ni, àwọ́n ẹbí òun sì gbé òun wá sí ilé ìjọsin náà, ó ní kò dùn mọ́ òun láti máa gbé sọ́ọ̀sì.
Ẹ̀wẹ̀, ìyá Adewale Monsurat sàlàyé pé, fúnra òun ni òun gbé ọmọ náà wá sí ilé ìjọsìn ọ̀hún fún àdúrà, nítorí ó máa ń dójú ti ẹbí láàrin ìgboro. Ìjọ ìbùkún rere ìwòsàn “Blessings of Goodness Healing Church” ni ijegun Isheri yìí ni àwọn ọlọ́pàá ti tú àwọn ènìyàn náà sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Bala Elkana tó jẹ́ agbẹnusọ àwọn ọlọ́pàá ṣe ṣàlàyé.
0 notes