Tumgik
#nàìjíríà
countriesgame · 9 months
Text
Please reblog for a bigger sample size!
If you have any fun fact about Nigeria, please tell us and I'll reblog it!
Be respectful in your comments. You can criticize a government without offending its people.
127 notes · View notes
aalawsng · 2 years
Text
Tumblr media
0 notes
edeyorubarewa · 5 years
Photo
Tumblr media
Fulani and Origin of the Names “Yoruba” and “Yamuri” By Farooq A. Kperogi, Ph.D. Twitter: @farooqkperogi Former Minister of Culture Femi Fani-Kayode started a healthy national conversation about the constructedness of collective identities in Nigeria when he repudiated his “Yoruba” identity because he said the name owes etymological debts to the Fulani and that it has pejorative denotations and connotations. This is, of course, both ahistorical and factually inaccurate. As I pointed out in my preliminary intervention on his claims on social media, the name “Yariba” was first attested in a treatise by a 16th-century Songhai Islamic scholar by the name of Ahmad Baba to refer to the people of the ancient Oyo Empire, which included all of present-day Oyo State, most of Osun State—and parts of Kwara and some western Nigerian states. Ahmad Baba’s 1613 essay, titled “Al-kashf wa-l-bayān li-aṣnāfmajlūb al-Sūdān” (translated into English as “The Exposition and Explanation Concerning the Varieties of Transported Black Africans”), mentioned “Yariba” among ethnic groups Muslims were justified to enslave. In his 1806 treatise titled "Bayan Wujub Al-Hijra,Ala L-Ibad,” Sheikh Usmanu Dan Fodiyo referenced Ahmad Baba’s essay and contested some of its claims. Ahmad Baba had written that “the people of Kano, some of Zakzak [Zaria?], the people of Katsina, the people of Gobir, and all of the Songhay” were Muslims who could never be enslaved. Since Dan Fodio didn’t think the Islam in Hausaland at the time was authentic, he needed to justify his jihad, so he responded to Ahmad Baba posthumously by asserting that what was true of Ahmadu Baba’s claims 200 years ago, “might not necessarily be true at all other times, since every scholar relates what he sees in his own days.” Dan Fodio’s son, Muhammad Bello, wrote Infaq al-mansur in 1813 where he also responded to Ahmad Baba’s 1613 essay, and had cause to mention “Yariba.” For the full story check the bio 👆👆👆 #Nàìjíríà #Yoruba #EdeYorubaRewa https://www.instagram.com/p/B4FT6YTp6mv/?igshid=2sgflcy9r9ya
0 notes
silentambassadors · 5 years
Photo
Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media Tumblr media
As a good illustration of one of the most diverse nations in the world, the Federal Republic of Nigeria emerged from a whole host of prior colonies and protectorates - and prior to that, a whole host of empires and kingdoms.  Even still today, some 250 different ethnic groups live in Nigeria, with at least as many languages spoken, plus various other sectarian divisions (Christian and Muslim, north and south, rural and urban, coastal and inland, etc.).  And alas, some of those divisions have led to great unrest and violence through the years.  Here’s hoping Nigeria can, one day, be an example of an “e pluribus unum” sort of state....
Stamp details: Top left: Issued in: 1874 From: Lagos, Lagos Colony MC #1
Top middle: Issued in: 1892 From: Old Calabar, Oil Rivers Protectorate MC #1
Top right: Issued in: 1893 From: Old Calabar, Niger Coast Protectorate MC #16
Second row left: Issued in: 1900 From: Zungeru, Northern Nigeria Protectorate MC #1
Second row middle: Issued in: 1901 From: Old Calabar, Southern Nigeria Protectorate MC #1
Second row left: Issued in: 1912 From: Lagos, Colony and Protectorate of Southern Nigeria MC #56
Third row: Issued on: June 1, 1914 From: Lagos, Colony and Protectorate of Nigeria MC #1
Fourth row left: Issued on: October 1, 1960 From: Lagos, Federation of Nigeria MC #91
Fourth row right: Issued on: October 1, 1965 From: Lagos, Federal Republic of Nigeria MC #172
Stamp on bottom: Issued in: 2014 From: Lagos, Federal Republic of Nigeria SC #864
Recognized as a sovereign state by the UN: Yes (since October 7, 1960) Official name: Federal Republic of Nigeria; Jamhuriyar Taraiyar Nijeriya; Ọ̀hàńjíkọ̀ Ọ̀hànézè Naìjíríyà; Orílẹ̀-èdè Olómìniira Àpapọ̀ Nàìjíríà Member of the Universal Postal Union: Yes (since July 10, 1961)
4 notes · View notes
naijanotes · 6 years
Photo
Tumblr media
Ọ̀RỌ̀ DÍRẸ̀ Bí ÀLÉKÚN NÍPA ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ: KÁ TÓ GBA ÒMÌNIRA ÀTI LẸ́YÌN ÒMÌNIRA (APÁ KÌÍNÍ) Kónkó jabele ni àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Nàìjíríà wà láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, kóówá ń ṣe tirẹ̀ ni, kó tó di pé àwọn òyìnbó amúniṣìn gòkè wá láti kó wa pọ̀ ní tipátipá lọ́jọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1901.
0 notes
naijablinks · 3 years
Text
KÀ NÍ KÚKÚRÚ NÍPA BÁYỌ̀ ÒDÒDÓ ( YORUBA VERSION)
KÀ NÍ KÚKÚRÚ NÍPA BÁYỌ̀ ÒDÒDÓ ( YORUBA VERSION)
Báyọ̀ Adéẹ̀yọ̀ tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Báyọ̀ Òdòdó jẹ́ olórin ìbílẹ̀ Nàìjíríà, oǹkọrin àti atẹdùrù. Lọ́wọ́ báyìí, ó ń kà láti gboyè kínní (first degree) láti Fáṣitì Nípa Ìmọ̀-Ẹ̀rọ ti Ládókè Akíntọ́lá (LAUTECH). A le tọpa iṣẹ́ orin tí Báyọ̀ Òdòdó yàn láàyò lọ ibi ìfẹ́ tó ní sí ohun èlò ìkọrin, ní pàtàkì jùlọ, dùrù. Nítorí lẹ́yìn tí ó jẹ́ gbajúgbajà atẹdùrù ló bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ sí yíyan iṣẹ́ orin…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
chefseyephotography · 6 years
Video
On this day 1 October 1960 the West African nation of Nigeria became free of British imperialism, at least on paper. The remnants of the former British Empire still can be felt throughout Nigeria and the influences of new cultural and economic colonial masters can be scene today via the US and China. It is high time that Nigerians the world over reclaim it's nation, it's resources and it's talents to build the shining star, that example on the hill top of Africa it was always meant to be. We can't go from a booming economy in the 1970's to now having the highest poverty rate in the world replacing India for that undistinguished position. Time to rise up Nigeria and Nigeiran to become what you were always destined to be. Happy 58th Anniversary Nigeria. 🎉🎈🇳🇬🇳🇬🇳🇬🎈🎉 Repost, @bbcnewsyoruba Òní ni ó pé ọdún méjìdínláàdọ́ta ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gba òminira. Kíní ìmọ̀ràn yín fún ìlọsíwájú orílẹ̀-èdè yìí. #Nigeria #CarpeDiem #RiseUpNigeria #NationBuilding #NigerianIndependanceDay #NaijaNoDeyCarryLast (at Abuja, Nigeria) https://www.instagram.com/p/BoZBOFElU7E/?utm_source=ig_tumblr_share&igshid=1ux8mwiq7evc9
1 note · View note
thedivineprince · 4 years
Photo
Tumblr media
Ifá ní àsàsí ni SARS àti SWAT... Ogúnlénírínwó SARS Ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀rin SWAT Wọ́n dárí jọ, wọ́n ńlọ bá àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà jagun. Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà kò jẹ, Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà kò mu; Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà ni yio ṣẹ́gun ogúnlénírínwó SARS #NigerianCrisis #EndSARS #EndPoliceBrutalityinNigeraNOW #StopKillingUs 💔💔💔 End SARS #EndSarsNow #EndSARS ✊🏾 🎩 #RespectTheVoodoo 🐍 #TheVoodooIsREAL #TwoSpiritConjuror ☥ #HoodooCentral #TheConjureMan #VoodooWorldWide #AfaVoodoo #RespectTheMedicine #RespectTheAncestors #AncestorsSEEyou #AncestorsSEEme #AncestorsSeeAll #WestAfricanVoodoo #RespectTheVoodoo #Respecterlevaudou #RespeiteOvodu #Respetaelvudú #traiteur #treateur #traiteus (at House of the Divine Prince) https://www.instagram.com/p/CGl86lIjXak/?igshid=1xeetgi7tlx9m
0 notes
ourbestnaijanews · 4 years
Photo
Tumblr media
Àyọ́jọ́ ọjọ́ Òmìnira Nàìjíríà: Sanwo-Olu gbàlejò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ̣ogọ́ta, El-Rufai dá ẹlẹ́wọ̀n 25 sílẹ̀ - BBC News Yorùbá
0 notes
newsnigeria · 4 years
Text
Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun
Tumblr media
Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun Fẹ́mi Akínṣọlá Gbajúgbajà onímọ̀ nípa ìṣègùn ìbílẹ̀ nílẹ̀ ẹ Yorùbá, tó tún jẹ́ Olóyè Àràbà nípìńlẹ̀ Oṣun. Ifáyemí Ẹlẹ́buùbọn ti gba ìpàdé ńlá àjọ̀dún ayẹyẹ àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oṣó àti àjẹ́ ní ìpínlẹ̀ Oṣun. Níbi ìpàdé yìí ni onímọ̀ ìṣègùn ìbílẹ̀ ti fi ọ̀rọ̀ léde pé ìtàjẹ̀sílẹ̀ léwu púpọ̀ fún ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè yìí. Nígbà tó ń bá ìpéjọpọ̀ náà ṣọ̀rọ̀ lọ́jọ́bọ ọse, èyí tó jẹ́ àkọ́kọ́ irú ayẹyẹ bẹ́ẹ̀ ti ẹgbẹ́ ìtẹ̀síwájú àwọn àjẹ́ àti oṣó ìpínlẹ̀ Oṣun, Ẹlẹ́buùbọn rọ Ìjọba àpapọ̀ láti tètè wá wọ́rọ́kọ́ fi ṣàdá lórí ìpànìyàn tó ń wáyé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ní kí wọ́n ṣe èyí kí Ìbínú Ọlọ́run tó sọkalẹ s’órí orílẹ̀-èdè. Gẹ́gẹ́ bí onifa yìí ṣe sọ ọ, wọ́n gbọdọ̀ tọwọ́ọ lemọ́ lemọ́ ìpànìyàn tó ń wáyé níhàa Àríwá orílẹ̀-èdè yìí àti ìpànìyàn fi ṣòògùn owó níhàa Gúúsù bọ aṣọ, kí àbámọ̀ má baà gbẹ̀yìn rẹ̀. Ó gba àwọn onímọ̀ ìṣègùn ìbílẹ̀ nímọ̀ràn láti mọ̀ dáadáa nípa ẹ̀sìn wọn, láti má fààyè gba ọ̀rọ̀ tí kò bá ohun tí wọ́n ń ṣe mu àti pé, kí wọ́n wà ní ìdúró déédé àti ṣíṣe òdodo pẹ̀lú àwọn èèyàn láti jẹ́ èèyàn ire láwùjọ. Ó ní gbogbo ẹ̀dá alààyè ló ní ẹgbẹ́ ọ̀run kan tàbí òmíràn tí wọ́n ń ṣe. Ó sì tẹnu mọ́ ọ pé mímọ ẹgbẹ́ ẹni dáadáa àti ṣíṣe ìfẹ́ inú wọn máa ń ran ìrìnàjò ẹ̀dá láyé lọ́wọ́. “Iye ìtàjẹ̀sílẹ̀ àti ìfini sẹ́ṣó owó ní Nàìjíríà ń kọ ni lóminú. Kí Ìjọba ní gboogbo ìpele mú òpin wá sí èyí, kí Elédùwà tó rọ̀jò ìbínú Rẹ̀ lé orílẹ̀-èdè lórí. Read the full article
0 notes
Photo
Tumblr media
Gbogbo ohun tí a bá ṣe loni, ọ̀rọ̀ ìtàn ni yóò dà lọ́la, ẹ Dákun ẹ má gbin igi oró èwe ńbọ̀ ó! Tí ìṣẹ́ ò bá jẹ́ ká sọ òdodo, àìṣòdodo kò ní jẹ́ ká bọ́ lọ́wọ́ ìṣẹ́. #aonepure #realme #amreal #mood #forever #itconfidence #notarrogant #notpride #BelieveinGodBelieveinyourself #onGod #truth #ọmọYorùbánimio #tọkàntọkàn #ọ̀rọ̀àgbà #awordisenoughforawiseman #behumble #fact #wisewords #deeply #takethat #bigfacts #life #Secrets #letlovereigns #togetherwepush #TogetherWeRise #letlovereigns #loveleads #justicefortina 💊🗝️🌱#NÀÌJÍRÍÀ 💔💔💔 (at Onelove) https://www.instagram.com/p/CA5EW_7ja45/?igshid=5cseonvepuf8
0 notes
heryordejy-blog · 7 years
Photo
Tumblr media
Nàìjíríà yí tí gbogbo wa ní (at Kwara)
0 notes
edeyorubarewa · 5 years
Video
Nínú eré wo ni fọ́nrán yìí wà. #TundeKelani #Yoruba #Nàìjíríà #Ibile #Saworoide #ÈdèYorùbárẹwà (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/B3CT75SpZnw/?igshid=q6tbdgjztqi2
0 notes
naijanotes · 6 years
Text
MO FẸ́ DI ÀÀRẸ NÀÌJÍRÍÀ NÍTORI……. ATIKU
MO FẸ́ DI ÀÀRẸ NÀÌJÍRÍÀ NÍTORI……. ATIKU
Ọ̀kan lára àwọn olùdíje sí ipò Ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, Alhaji Atiku Abubakar ti sọ n’ilu Abuja lánàá pé ìdí pàtàkì tí òun fi fẹ́ di Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà ni láti tún ìgbésí ayé àwọn mẹ̀kúnnù ṣe nítorí àwọn ni pàṣán àìṣedéédé ọrọ̀ ajé Nàìjíríà ń gbó mọ́ lára jù lọ.
Abuja ló ti sàlàyé ọ̀rọ̀ yi níbi ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan táwọn ẹgbẹ́ kan tí a mọ̀ sí United Nigeria Group pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn…
View On WordPress
0 notes
alenasbdesign · 2 years
Photo
Tumblr media
Happy Democracy Day, Nigeria!
0 notes
edeyorubarewa · 5 years
Video
Nínú eré wo ni fọ́nrán yìí wà. #TundeKelani #Yoruba #Nàìjíríà #Ibile #Saworoide #ÈdèYorùbárẹwà https://www.instagram.com/p/B3CTRJ4Jon7/?igshid=parvi9dw1t4l
0 notes