#Omo-Alata
Explore tagged Tumblr posts
Text
Mohbad & Zlatan - Account Balance Lyrics
Mohbad & Zlatan - Account Balance Lyrics Account balance loje kin ma buga bayi Backward never Naira yato si sefa Imole zaku na lamba Imole Apa ti jabo o Jesus Awon kan lon fori fogo yeee Ewa wo cause trouble yeee Oti ko sinu alata wa Apa ti jabo ye Awon Kan lon fori fogo yeee Ewa wo cause trouble yeee Oti ko sinu alata wa Apa ti jabo o Jesu Ngbo kilo gba wa sinu table Oja wire oja cable Eni olowo lowo owa disable Gucci oyato si bata Jesu Over confidence ma Jo aseju Ice lorun mi oleku Asiwaju bi tinubu Sunday odagboru mo bayi Owo ni Monday mi wa bayi Omo Alfa gan o gee mo bayi Awon nepa gan oni na bayii Account balance loje kin ma buga bayi Backward never Naira yato si sefa Imole zaku na lamba Kuro nbe see Impossibility Ota mi oni bori Abi ani leti gbo adugbo yin Suwagu dripping oru bleeding Moti ni Omo kan aladugbo yin Gbagbe highland lo bere mainland Ja wo anywere tio bayo paper Omo ale loma ko ti Le ta Fun eyin tio yee oma yee yin later Imole ko kuku bole Eku niwon won ma je sole Basket no fit fetch water like bucket Sunday odagboru mo bayi Owo ni Monday mi wa bayi Omo Alfa gan gee mo bayi Awon nepa gan oni na Account balance loje kin ma buga bayi Backward never Naira yato si sefa Imole zaku na lamba 1 2 3 oma fo Eni loyun lo ma sun Eni bimo oron lo ma Pon Lamba todun won ni Le ko Kilode ojere Ah no small ni gboro ko lo bere Jaye mi kan to fun fere Ti ba sise kin ma rere Apa ti jabo o Jesu Awon Kan lon fori fogo yeee Ewa wo cause trouble yin Oti ko sinu alata wa Apa ti jabo yeee Awon kan lon fori fogo yeee Ewa wo cause trouble yin Oti ko sinu alata wa Sunday odagboru mo bayi Owo ni Monday mi wa bayi Omo Alfa gan gee mo Awon nepa gan oni na Lamba Read the full article
0 notes
Text
Olatorera Oniru Founder, Dress Me Outlet
Olatorera Oniru
Olatorera Oniru is a 30-year-old highly-rated Nigerian entrepreneur. As CEO of Dressmeoutlet.com, she is passionately driven and Afro-centric. She constantly pushes for the appreciation of Africa ideas and innovation. A member of The National Scholars Honor Society USA, Olatorera flourished her career working for two Fortune Top 5 companies…
View On WordPress
#Achievers Media#Alfa O & O Networks; Glazed the Doughnut Café#Andela#BellaNaija#CEO&039;s#Dressmeoutlet.com#Gamsole#Hotels.com.ng#Mark Essien#Olatorera Oniru#Omo-Alata#Prepclass#Rex Idaminabo#Start-ups in Nigeria#Uche Pedro
0 notes
Text
Iseda Ọ̀rọ̀ Orúkọ
Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ
1) Àwa Yoruba s'eda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere, afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe àti àpe tún pe kíkún
2) Àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda nípa lílo afọmọ ibere :ai àti òní.
Fún àpẹẹrẹ
Ai
Kú
Aiku
Ai
Jẹun
Aijeun
Ai
Lowo
Ailowo
Ai
Là
Aila
Ai
Sun
Aisun
Ai
Gbogbo
Aigbagbo
3) iseda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere òní àti orúkọ
Fún àpẹẹrẹ
Oni
Isu
Onisu
Oni
Ile
Onílé
Oni
Ata
Alata
Oni
Omo
Olomo
Oni
Aya
Alaya
Oni
Oko
Oloko
4) Iseda ọ̀rọ̀ orúkọ nípa lílo afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe
Fún àpẹẹrẹ
Oro orúkọ
Afọmọ àárín
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Ìṣe
Ki
Ise
Isekise
Ilé
Ki
Ilé
Ilekile
Aṣọ
Ki
Aso
Asokaso
Ọmọ
Ki
Omo
Omokomo
Aya
Ki
Aya
Ayakaya
5) iseda oro orúkọ nípa pípa ọ̀rọ̀ orúkọ méjì pò láti di oro orúkọ kan.
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Etí
Odò
Etido
Eti
Ike
etile
Eti
Okun
Etíkun
Ojú
Ode
Ojúde
Ọmọ
Ọkùnrin
Ọmọkùnrin
6) iseda oro orúkọ èyí tí aranmo máa wáyé
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Ilé
Ìwé
Iléèwé
Ilé
Ìṣe
Ileese
Ara
Oko
Arooko
Àyà
Ọba
Ayaaba
Ìyá
Ègbé
Iyaegbe
Ara
Ilé
Araale
7) iseda oro orúkọ nípa lílo apetunpe oro ìṣe àti oro ìṣe láti di ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Fún àpẹẹrẹ
Àpólà oro ìṣe
Àpólà oro ìṣe
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Jagun
Jagun
Jagunjagun
Wole
Wole
Wolewole
Kólé
Kólé
Kokekole
Kọrin
Kọrin
Korinkorin
Pana
Pana
Panapana
Gbomo
Gbomo
Gbomogbomo
Tafa
Tafa
Tafatafa
Lagi
Lagi
Lagilagi
I
via Blogger http://ift.tt/2irGbB3
0 notes
Text
Iseda Ọ̀rọ̀ Orúkọ ni èdè Yorùbá
Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ 1) Àwa Yoruba s'eda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere, afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe àti àpe tún pe kíkún 2) Àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda nípa lílo afọmọ ibere :ai àti òní. Fún àpẹẹrẹ Ai Kú Aiku Ai Jẹun Aijeun Ai Lowo Ailowo Ai Là Aila Ai Sun Aisun Ai Gbogbo Aigbagbo 3) iseda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere òní àti orúkọ Fún àpẹẹrẹ Oni Isu Onisu Oni Ile Onílé Oni Ata Alata Oni Omo Olomo Oni Aya Alaya Oni Oko Oloko 4) Iseda ọ̀rọ̀ orúkọ nípa lílo afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe Fún àpẹẹrẹ Oro orúkọ Afọmọ àárín Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Ìṣe Ki Ise Isekise Ilé Ki Ilé Ilekile Aṣọ Ki Aso Asokaso Ọmọ Ki Omo Omokomo Aya Ki Aya Ayakaya 5) iseda oro orúkọ nípa pípa ọ̀rọ̀ orúkọ méjì pò láti di oro orúkọ kan. Fún àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Etí Odò Etido Eti Ike etile Eti Okun Etíkun Ojú Ode Ojúde Ọmọ Ọkùnrin Ọmọkùnrin 6) iseda oro orúkọ èyí tí aranmo máa wáyé Fún àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Ilé Ìwé Iléèwé Ilé Ìṣe Ileese Ara Oko Arooko Àyà Ọba Ayaaba Ìyá Ègbé Iyaegbe Ara Ilé Araale 7) iseda oro orúkọ nípa lílo apetunpe oro ìṣe àti oro ìṣe láti di ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Fún àpẹẹrẹ Àpólà oro ìṣe Àpólà oro ìṣe Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Jagun Jagun Jagunjagun Wole Wole Wolewole Kólé Kólé Kokekole Kọrin Kọrin Korinkorin Pana Pana Panapana Gbomo Gbomo Gbomogbomo Tafa Tafa Tafatafa Lagi Lagi Lagilagi via Blogger http://ift.tt/2h14Dc8
0 notes
Text
Iseda Ọ̀rọ̀ Orúkọ
Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ 1) Àwa Yoruba s'eda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere, afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe àti àpe tún pe kíkún 2) Àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda nípa lílo afọmọ ibere :ai àti òní. Fún àpẹẹrẹ Ai Kú Aiku Ai Jẹun Aijeun Ai Lowo Ailowo Ai Là Aila Ai Sun Aisun Ai Gbogbo Aigbagbo 3) iseda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere òní àti orúkọ Fún àpẹẹrẹ Oni Isu Onisu Oni Ile Onílé Oni Ata Alata Oni Omo Olomo Oni Aya Alaya Oni Oko Oloko 4) Iseda ọ̀rọ̀ orúkọ nípa lílo afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe Fún àpẹẹrẹ Oro orúkọ Afọmọ àárín Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Ìṣe Ki Ise Isekise Ilé Ki Ilé Ilekile Aṣọ Ki Aso Asokaso Ọmọ Ki Omo Omokomo Aya Ki Aya Ayakaya 5) iseda oro orúkọ nípa pípa ọ̀rọ̀ orúkọ méjì pò láti di oro orúkọ kan. Fún àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Etí Odò Etido Eti Ike etile Eti Okun Etíkun Ojú Ode Ojúde Ọmọ Ọkùnrin Ọmọkùnrin 6) iseda oro orúkọ èyí tí aranmo máa wáyé Fún àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Ilé Ìwé Iléèwé Ilé Ìṣe Ileese Ara Oko Arooko Àyà Ọba Ayaaba Ìyá Ègbé Iyaegbe Ara Ilé Araale 7) iseda oro orúkọ nípa lílo apetunpe oro ìṣe àti oro ìṣe láti di ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Fún àpẹẹrẹ Àpólà oro ìṣe Àpólà oro ìṣe Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda Jagun Jagun Jagunjagun Wole Wole Wolewole Kólé Kólé Kokekole Kọrin Kọrin Korinkorin Pana Pana Panapana Gbomo Gbomo Gbomogbomo Tafa Tafa Tafatafa Lagi Lagi Lagilagi via Blogger http://ift.tt/2A4lpyG
0 notes